Nehemaya 9:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Jeṣua, Bani, ati Kadimieli, Ṣebanaya, Bunni, Ṣerebaya, Bani, ati Kenani dúró lórí pèpéle àwọn ọmọ Lefi, wọ́n sì gbadura sókè sí OLUWA Ọlọrun wọn.

Nehemaya 9

Nehemaya 9:1-11