Nehemaya 9:23 BIBELI MIMỌ (BM)

O jẹ́ kí ìrandíran wọn pọ̀ sí i bí ìràwọ̀ ojú ọ̀run, o sì kó wọn dé ilẹ̀ tí o ti ṣèlérí fún àwọn baba wọn pé wọn yóo lọ gbà.

Nehemaya 9

Nehemaya 9:18-33