Nehemaya 9:20 BIBELI MIMỌ (BM)

O fún wọn ní ẹ̀mí rere rẹ láti máa kọ́ wọn, o kò dá mana rẹ dúró, o fi ń bọ́ wọn. O sì ń fún wọn ni omi mu nígbà tí òùngbẹ bá ń gbẹ wọ́n.

Nehemaya 9

Nehemaya 9:15-22