Nehemaya 9:14 BIBELI MIMỌ (BM)

O kọ́ wọn láti máa pa ọjọ́ ìsinmi rẹ mọ́, o sì tún pèsè ẹ̀kọ́, ìlànà, ati òfin fún wọn láti ọwọ́ Mose iranṣẹ rẹ.

Nehemaya 9

Nehemaya 9:6-24