Nehemaya 9:11 BIBELI MIMỌ (BM)

O pín òkun sí meji níwájú wọn, kí wọ́n lè gba ààrin rẹ̀ kọjá lórí ilẹ̀ gbígbẹ, o sì sọ àwọn tí wọn ń lé wọn lọ sinu ibú bí ẹni sọ òkúta sinu omi.

Nehemaya 9

Nehemaya 9:10-12