Nehemaya 9:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kẹrinlelogun oṣù kan náà, àwọn ọmọ Israẹli péjọ pọ̀, wọ́n gbààwẹ̀, wọ́n wọ aṣọ ọ̀fọ̀, wọ́n sì ku eruku sí orí wọn.

Nehemaya 9

Nehemaya 9:1-11