Nehemaya 8:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Lefi rẹ àwọn eniyan náà lẹ́kún, wọ́n sọ fún wọn pé, “Ẹ dákẹ́, nítorí pé ọjọ́ mímọ́ ni ọjọ́ òní, ẹ má bọkàn jẹ́.”

Nehemaya 8

Nehemaya 8:1-18