Nehemaya 7:58-60 BIBELI MIMỌ (BM)

58. àwọn ọmọ Jaala, àwọn ọmọ Dakoni, ati àwọn ọmọ Gideli,

59. àwọn ọmọ Ṣefataya, àwọn ọmọ Hatili, àwọn ọmọ Pokereti Hasebaimu, ati àwọn ọmọ Amoni.

60. Gbogbo àwọn tí wọn ń ṣe iṣẹ́ iranṣẹ ninu tẹmpili ati àwọn ọmọ àwọn iranṣẹ Solomoni jẹ́ irinwo ó dín mẹjọ (392).

Nehemaya 7