Nehemaya 7:36-38 BIBELI MIMỌ (BM)

36. Àwọn ọmọ Jẹriko jẹ́ ojilelọọdunrun ó lé marun-un (345).

37. Àwọn ọmọ Lodi, Hadidi ati Ono jẹ́ ẹẹdẹgbẹrin ó lé mọkanlelogun (721).

38. Àwọn ọmọ Senaa jẹ́ ẹgbaaji ó dín aadọrin (3,930).

Nehemaya 7