Nehemaya 7:32-34 BIBELI MIMỌ (BM)

32. Àwọn ará Bẹtẹli ati Ai jẹ́ mẹtalelọgọfa (123).

33. Àwọn ará Nebo keji jẹ́ mejilelaadọta.

34. Àwọn ọmọ Elamu keji jẹ́ ẹgbẹfa ó lé mẹrinlelaadọta (1,254).

Nehemaya 7