Nehemaya 7:29-32 BIBELI MIMỌ (BM)

29. Àwọn ará Kiriati Jearimu ati Kefira ati Beeroti jẹ́ ọtadinlẹgbẹrin ó lé mẹta (743).

30. Àwọn ará Rama ati Geba jẹ́ ẹgbẹta lé mọkanlelogun (621).

31. Àwọn ará Mikimaṣi jẹ́ mejilelọgọfa (122).

32. Àwọn ará Bẹtẹli ati Ai jẹ́ mẹtalelọgọfa (123).

Nehemaya 7