Nehemaya 7:16-18 BIBELI MIMỌ (BM)

16. Àwọn ọmọ Bebai jẹ́ ẹgbẹta lé mejidinlọgbọn (628).

17. Àwọn ọmọ Asigadi jẹ́ ẹgbaa ó lé ọọdunrun ati mejilelogun (2,322).

18. Àwọn ọmọ Adonikamu jẹ́ ọtalelẹgbẹta ati meje (667).

Nehemaya 7