Nehemaya 6:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ranṣẹ pada sí i pé, “Ohun tí ó jọ bẹ́ẹ̀ kò ṣẹlẹ̀ rárá, o kàn sọ ohun tí o rò lọ́kàn ara rẹ ni.”

Nehemaya 6

Nehemaya 6:5-9