Nehemaya 5:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn mìíràn ń sọ pé, “A ti fi ilẹ̀ oko wa yáwó, ati ọgbà àjàrà wa, ati ilé wa, kí á lè rówó ra ọkà nítorí ìyàn tí ó mú yìí.”

Nehemaya 5

Nehemaya 5:2-7