Nehemaya 5:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ara ni mo fi bá wọn ṣiṣẹ́ odi mímọ, sibẹ n kò gba ilẹ̀ kankan, gbogbo àwọn iranṣẹ mi náà sì péjú sibẹ láti ṣiṣẹ́.

Nehemaya 5

Nehemaya 5:8-18