Nehemaya 4:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ibikíbi tí ẹ bá wà, tí ẹ bá ti gbọ́ fèrè, ẹ wá péjọ sọ́dọ̀ wa. Ọlọrun wa yóo jà fún wa.”

Nehemaya 4

Nehemaya 4:12-23