Nehemaya 4:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Sanbalati gbọ́ pé a ti ń kọ́ odi náà, inú bíi gidigidi, ó bá bẹ̀rẹ̀ sí bu ẹnu àtẹ́ lu àwọn Juu.

Nehemaya 4

Nehemaya 4:1-3