Nehemaya 3:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn wọn, àwọn ará Tekoa ṣe àtúnṣe ọ̀dọ̀ tiwọn, ṣugbọn àwọn ọlọ́lá ààrin wọn kò lọ́wọ́ sí iṣẹ́ àtúnṣe náà.

Nehemaya 3

Nehemaya 3:4-10