Nehemaya 3:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ibẹ̀ ni àwọn ará Jẹriko ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́. Lẹ́yìn wọn ni Sakuri ọmọ Imiri bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́, ó mọ abala tí ó tẹ̀lé e.

Nehemaya 3

Nehemaya 3:1-12