Nehemaya 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí Sanbalati ará Horoni ati Tobaya iranṣẹ ọba, ará Amoni gbọ́, inú bí wọn pé ẹnìkan lè máa wá alaafia àwọn ọmọ Israẹli.

Nehemaya 2

Nehemaya 2:3-20