Nehemaya 13:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo bá pàṣẹ pé kí wọ́n tún yàrá náà ṣe kí ó mọ́, ẹ̀yìn náà ni mo wá kó àwọn ohun èlò ilé Ọlọrun pada ati ọrẹ ẹbọ ohun sísun ati turari.

Nehemaya 13

Nehemaya 13:1-12