Nehemaya 13:7 BIBELI MIMỌ (BM)

mo sì wá sí Jerusalẹmu, ìgbà náà ni mo wá rí nǹkan burúkú tí Eliaṣibu ṣe nítorí Tobaya, tí ó yọ yàrá fún ninu àgbàlá ilé Ọlọrun.

Nehemaya 13

Nehemaya 13:4-15