Nehemaya 13:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ó tó di àkókò náà, Eliaṣibu alufaa, tí wọ́n yàn láti máa ṣe àkóso àwọn yàrá ilé Ọlọrun wa, tí ó sì ní àjọṣe pẹlu Tobaya,

Nehemaya 13

Nehemaya 13:1-8