Nehemaya 13:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo bá àwọn ọlọ́lá Juda wí, mo ní, “Irú nǹkan burúkú wo ni ẹ̀ ń ṣe yìí, tí ẹ̀ ń rú òfin ọjọ́ ìsinmi?

Nehemaya 13

Nehemaya 13:12-24