Nehemaya 13:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun mi, ranti mi, nítorí nǹkan wọnyi, kí o má sì pa gbogbo nǹkan rere tí mo ti ṣe sí tẹmpili rẹ rẹ́ ati àwọn iṣẹ́ ìsìn rẹ̀.

Nehemaya 13

Nehemaya 13:9-21