Nehemaya 13:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, mo bá àwọn olórí wí, mo ní “Kí ló dé tí ilé Ọlọrun fi di àpatì?” Mo kó wọn jọ, mo sì dá wọn pada sí ààyè wọn.

Nehemaya 13

Nehemaya 13:2-18