Nehemaya 12:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo nǹkan wọnyi ṣẹlẹ̀ nígbà ayé Joiakimu, ọmọ Jeṣua, ọmọ Josadaki, ati nígbà ayé Nehemaya, gomina, ati Ẹsira Alufaa ati akọ̀wé.

Nehemaya 12

Nehemaya 12:17-27