Nehemaya 12:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Orúkọ àwọn alufaa ati àwọn ọmọ Lefi tí wọ́n bá Serubabeli ọmọ Ṣealitieli ati Jeṣua dé nìwọ̀nyí: Seraaya, Jeremaya ati Ẹsira,

Nehemaya 12

Nehemaya 12:1-6