Nehemaya 11:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn rẹ̀ ni Gabai ati Salai. Àpapọ̀ gbogbo àwọn ọmọ Bẹnjamini wá jẹ́ ẹẹdẹgbẹrun ó lé mejidinlọgbọn (928).

Nehemaya 11

Nehemaya 11:5-11