Nehemaya 11:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn aṣọ́nà ni, Akubu, Talimoni ati àwọn arakunrin wọn, àwọn ni wọ́n ń ṣọ́ àwọn ẹnu ọ̀nà, wọ́n jẹ́ mejilelaadọsan-an (172).

Nehemaya 11

Nehemaya 11:13-23