Nehemaya 11:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣabetai ati Josabadi, láàrin àwọn olórí ọmọ Lefi, ni wọ́n ń bojútó àwọn iṣẹ́ òde ilé Ọlọrun.

Nehemaya 11

Nehemaya 11:6-21