Nehemaya 11:14 BIBELI MIMỌ (BM)

ati àwọn arakunrin rẹ̀. Alágbára ati akọni eniyan ni wọ́n, wọ́n jẹ́ mejidinlaadoje (128). Sabidieli ọmọ Hagedolimu ni alabojuto wọn.

Nehemaya 11

Nehemaya 11:8-19