Nehemaya 10:35 BIBELI MIMỌ (BM)

A ti gbà á bí ojúṣe wa pé àkọ́so èso ilẹ̀ wa ati àkọ́so gbogbo èso igi wa lọdọọdun, ni a óo máa gbé wá sí ilé OLUWA.

Nehemaya 10

Nehemaya 10:27-39