Nehemaya 10:14-20 BIBELI MIMỌ (BM)

14. Àwọn ìjòyè wọn tí wọ́n fọwọ́ sí ìwé náà ni: Paroṣi, Pahati Moabu, Elamu, Satu, ati Bani,

15. Bunni, Asigadi, ati Bebai,

16. Adonija, Bigifai, ati Adini,

17. Ateri, Hesekaya ati Aṣuri,

18. Hodaya, Haṣumu, ati Besai,

19. Harifi, Anatoti, ati Nebai,

20. Magipiaṣi, Meṣulamu, ati Hesiri,

Nehemaya 10