Nehemaya 10:12-17 BIBELI MIMỌ (BM)

12. Sakuri, Ṣerebaya, ati Ṣebanaya,

13. Hodaya, Bani, ati Beninu.

14. Àwọn ìjòyè wọn tí wọ́n fọwọ́ sí ìwé náà ni: Paroṣi, Pahati Moabu, Elamu, Satu, ati Bani,

15. Bunni, Asigadi, ati Bebai,

16. Adonija, Bigifai, ati Adini,

17. Ateri, Hesekaya ati Aṣuri,

Nehemaya 10