11. Mika, Rehobu, ati Haṣabaya,
12. Sakuri, Ṣerebaya, ati Ṣebanaya,
13. Hodaya, Bani, ati Beninu.
14. Àwọn ìjòyè wọn tí wọ́n fọwọ́ sí ìwé náà ni: Paroṣi, Pahati Moabu, Elamu, Satu, ati Bani,
15. Bunni, Asigadi, ati Bebai,
16. Adonija, Bigifai, ati Adini,