Nehemaya 10:1-7 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Àwọn tí wọ́n fi ọwọ́ sí ìwé náà tí wọ́n sì fi èdìdì dì í nìwọ̀nyí: Nehemaya, gomina, ọmọ Hakalaya, ati Sedekaya.

2. Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ alufaa wọnyi: Seraya, Asaraya, ati Jeremaya,

3. Paṣuri, Amaraya, ati Malikija,

4. Hatuṣi, Ṣebanaya, ati Maluki,

5. Harimu, Meremoti, ati Ọbadaya,

6. Daniẹli, Ginetoni, ati Baruku,

7. Meṣulamu, Abija, ati Mijamini,

Nehemaya 10