Nahumu 3:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ọpọlọpọ ìwà àgbèrè Ninefe,tí wọ́n fanimọ́ra,ṣugbọn tí wọ́n kún fún òògùn olóró,ni gbogbo ìjìyà yìí ṣe dé bá a;nítorí ó ń fi ìwà àgbèrè rẹ̀ tan àwọn orílẹ̀-èdè jẹ,ó sì ń fi òògùn rẹ̀ mú àwọn eniyan.

Nahumu 3

Nahumu 3:1-10