Nahumu 3:16 BIBELI MIMỌ (BM)

O ti wá kún àwọn oníṣòwò rẹ, wọ́n sì pọ̀ ju ìràwọ̀ ojú ọ̀run lọ! Ṣugbọn wọ́n ti na ìyẹ́ wọn bí eṣú, wọ́n sì fò lọ.

Nahumu 3

Nahumu 3:15-19