Nahumu 2:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Akọ kinniun a máa fa ẹran yafún àwọn ọmọ rẹ̀,a sì máa lọ́ ẹran lọ́rùn pafún àwọn abo rẹ̀;a máa kó ẹran tí ó bá paati èyí tí ó fàya sinu ihò rẹ̀.

Nahumu 2

Nahumu 2:4-13