Nahumu 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

A ti pa Ninefe run! Ó ti dahoro!Ọkàn àwọn eniyan ti dàrú,orúnkún wọn ń gbọ̀n pẹ̀pẹ̀,ìrora dé bá ọpọlọpọ,gbogbo ojú wọn sì rẹ̀wẹ̀sì.

Nahumu 2

Nahumu 2:1-13