Nahumu 2:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Atúniká ti gbógun tì ọ́, ìwọ Ninefe.Yan eniyan ṣọ́ ibi ààbò;máa ṣọ́nà, di àmùrè rẹ,kí o sì múra ogun.

Nahumu 2

Nahumu 2:1-11