Nahumu 1:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí odò tí ó kún bo bèbè rẹ̀ni yóo ṣe mú ìparun bá àwọn ọ̀tá rẹ̀;yóo sì lépa àwọn ọ̀tá rẹ̀ bọ́ sí inú òkùnkùn.

Nahumu 1

Nahumu 1:3-15