Nahumu 1:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn òkè ńláńlá mì tìtì níwájú rẹ̀,àwọn òkè kéékèèké sì yọ́.Ilẹ̀ di asán níwájú rẹ̀,ayé ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀ di òfo.

Nahumu 1

Nahumu 1:1-7