Nahumu 1:3 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA kì í tètè bínú;ó lágbára lọpọlọpọ,kì í sìí dá ẹni tí ó bá jẹ̀bi láre.Ipa ọ̀nà rẹ̀ wà ninu ìjì ati ẹ̀fúùfù líle,awọsanma sì ni eruku ẹsẹ̀ rẹ̀.

Nahumu 1

Nahumu 1:1-7