Mika 7:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ tí a óo bá mọ odi ìlú yín, ẹ̀yin ará Jerusalẹmu, ọjọ́ náà ni a óo sún ààlà yín siwaju.

Mika 7

Mika 7:9-13