Mika 6:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọlọ́rọ̀ yín kún fún ìwà ipá; òpùrọ́ ni gbogbo àwọn ará ìlú, ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn sì kún ẹnu wọn.

Mika 6

Mika 6:2-16