Mika 5:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ náà, n óo pa àwọn ẹṣin yín run, n óo sì run gbogbo kẹ̀kẹ́ ogun yín.

Mika 5

Mika 5:2-15