Mika 4:6 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní, “Nígbà tí ó bá yá, n óo kó gbogbo àwọn arọ jọ, n óo kó àwọn tí mo ti túká jọ, ati àwọn tí mo ti pọ́n lójú.

Mika 4

Mika 4:2-8