Mika 4:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó bá yá, a óo fìdí òkè ilé OLUWA múlẹ̀bí òkè tí ó ga jùlọ,a óo gbé e ga ju àwọn òkè yòókù lọ,àwọn eniyan yóo sì máa wọ́ wá sibẹ.

Mika 4

Mika 4:1-7